61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+
Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+
Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,
Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,
Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+
-
1 Pétérù 2:9
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àmọ́ ẹ̀yin ni “àwọn èèyàn tí Ọlọ́run yàn, ẹgbẹ́ àlùfáà aládé, orílẹ̀-èdè mímọ́,+ àwùjọ àwọn èèyàn tó jẹ́ ohun ìní pàtàkì,+ kí ẹ lè kéde káàkiri àwọn ọlá ńlá”+ Ẹni tó pè yín jáde kúrò nínú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀ àgbàyanu rẹ̀.+