Àìsáyà 56:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Afọ́jú ni àwọn olùṣọ́ rẹ̀,+ ìkankan nínú wọn ò kíyè sí i.+ Ajá tí kò lè fọhùn ni gbogbo wọn, wọn ò lè gbó.+ Wọ́n ń mí hẹlẹ, wọ́n sì dùbúlẹ̀; wọ́n fẹ́ràn oorun. Jeremáyà 4:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Nítorí àwọn èèyàn mi gọ̀;+Wọn ò kà mí sí. Ọmọ tí kò gbọ́n ni wọ́n, wọn ò sì lóye. Ọ̀jáfáfá* ni wọ́n nínú ìwà ibi,Àmọ́, wọn ò mọ bí a ti ń ṣe rere.” Ìsíkíẹ́lì 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ọmọ èèyàn, àárín ọlọ̀tẹ̀ ilé lò ń gbé. Wọ́n ní ojú láti rí, àmọ́ wọn ò ríran, wọ́n ní etí láti gbọ́, àmọ́ wọn ò gbọ́ràn,+ torí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n.+
10 Afọ́jú ni àwọn olùṣọ́ rẹ̀,+ ìkankan nínú wọn ò kíyè sí i.+ Ajá tí kò lè fọhùn ni gbogbo wọn, wọn ò lè gbó.+ Wọ́n ń mí hẹlẹ, wọ́n sì dùbúlẹ̀; wọ́n fẹ́ràn oorun.
22 “Nítorí àwọn èèyàn mi gọ̀;+Wọn ò kà mí sí. Ọmọ tí kò gbọ́n ni wọ́n, wọn ò sì lóye. Ọ̀jáfáfá* ni wọ́n nínú ìwà ibi,Àmọ́, wọn ò mọ bí a ti ń ṣe rere.”
2 “Ọmọ èèyàn, àárín ọlọ̀tẹ̀ ilé lò ń gbé. Wọ́n ní ojú láti rí, àmọ́ wọn ò ríran, wọ́n ní etí láti gbọ́, àmọ́ wọn ò gbọ́ràn,+ torí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n.+