Sáàmù 102:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó ń bojú wolẹ̀ láti ibi gíga rẹ̀ mímọ́,+Láti ọ̀run, Jèhófà ń wo ayé,20 Kí ó lè gbọ́ bí ẹlẹ́wọ̀n ṣe ń kérora,+Kí ó lè dá àwọn tí wọ́n ti dájọ́ ikú fún sílẹ̀,+
19 Ó ń bojú wolẹ̀ láti ibi gíga rẹ̀ mímọ́,+Láti ọ̀run, Jèhófà ń wo ayé,20 Kí ó lè gbọ́ bí ẹlẹ́wọ̀n ṣe ń kérora,+Kí ó lè dá àwọn tí wọ́n ti dájọ́ ikú fún sílẹ̀,+