ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 12:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+

      Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+

      Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,

      Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+

  • Hósíà 13:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ṣùgbọ́n èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ láti ilẹ̀ Íjíbítì wá;+

      Ìwọ kò sì mọ Ọlọ́run mìíràn àfi èmi,

      Lẹ́yìn mi kò sí olùgbàlà kankan.+

  • 1 Tímótì 2:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+

  • Júùdù 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ọlọ́run kan ṣoṣo tó jẹ́ Olùgbàlà wa nípasẹ̀ Jésù Kristi Olúwa wa, ni kí ògo, ọlá, agbára àti àṣẹ máa jẹ́ tirẹ̀ láti ayérayé àti nísinsìnyí àti títí láé. Àmín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́