ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 37:37, 38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Torí náà, Senakérúbù ọba Ásíríà kúrò níbẹ̀, ó pa dà sí Nínéfè,+ ó sì ń gbé ibẹ̀.+ 38 Bó ṣe ń forí balẹ̀ ní ilé* Nísírọ́kì ọlọ́run rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀, Adiramélékì àti Ṣárésà fi idà pa á,+ wọ́n sì sá lọ sí ilẹ̀ Árárátì.+ Esari-hádónì+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

  • Àìsáyà 45:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ẹ kóra jọ, kí ẹ sì wá.

      Ẹ jọ sún mọ́ tòsí, ẹ̀yin tí ẹ yè bọ́ látinú àwọn orílẹ̀-èdè.+

      Wọn ò mọ nǹkan kan, àwọn tó ń gbé ère gbígbẹ́ kiri,

      Tí wọ́n sì ń gbàdúrà sí ọlọ́run tí kò lè gbà wọ́n.+

  • Àìsáyà 46:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Wọ́n gbé e sí èjìká wọn,+

      Wọ́n gbé e, wọ́n sì fi sí àyè rẹ̀, ṣe ló kàn dúró síbẹ̀.

      Kì í kúrò ní àyè rẹ̀.+

      Wọ́n ké sí i, àmọ́ kò dáhùn;

      Kò lè gba ẹnikẹ́ni nínú wàhálà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́