2 Sámúẹ́lì 15:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Dáfídì gbọ́ pé: “Áhítófẹ́lì wà lára àwọn tí ó dìtẹ̀+ pẹ̀lú Ábúsálómù.”+ Ni Dáfídì bá sọ pé: “Jèhófà,+ jọ̀wọ́ sọ ìmọ̀ràn* Áhítófẹ́lì di ti òmùgọ̀!”+ Àìsáyà 29:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, èmi ni Ẹni tó tún máa ṣe àwọn ohun àgbàyanu sí àwọn èèyàn yìí,+Ohun àgbàyanu kan tẹ̀ lé òmíràn;Ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n wọn máa ṣègbé,Òye àwọn olóye wọn sì máa fara pa mọ́.”+
31 Dáfídì gbọ́ pé: “Áhítófẹ́lì wà lára àwọn tí ó dìtẹ̀+ pẹ̀lú Ábúsálómù.”+ Ni Dáfídì bá sọ pé: “Jèhófà,+ jọ̀wọ́ sọ ìmọ̀ràn* Áhítófẹ́lì di ti òmùgọ̀!”+
14 Torí náà, èmi ni Ẹni tó tún máa ṣe àwọn ohun àgbàyanu sí àwọn èèyàn yìí,+Ohun àgbàyanu kan tẹ̀ lé òmíràn;Ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n wọn máa ṣègbé,Òye àwọn olóye wọn sì máa fara pa mọ́.”+