Sáàmù 147:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ń kọ́ Jerúsálẹ́mù;+Ó ń kó àwọn tí wọ́n fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ.+