Diutarónómì 4:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ẹ̀yin fúnra yín ti rí nǹkan wọ̀nyí kí ẹ lè mọ̀ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́;+ kò sí ẹlòmíì àfi òun nìkan.+ Diutarónómì 4:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Torí náà, kí o mọ̀ lónìí, kí o sì fi sọ́kàn pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́ lókè ọ̀run àti lórí ilẹ̀ ayé.+ Kò sí ẹlòmíì.+ Diutarónómì 32:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ẹ rí i báyìí pé èmi, àní èmi ni ẹni náà,+Kò sí ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Mo lè pani, mo sì lè sọni di alààyè.+ Mo lè dá ọgbẹ́+ síni lára, mo sì lè woni sàn,+Kò sí ẹnì kankan tó lè gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ mi.+
35 Ẹ̀yin fúnra yín ti rí nǹkan wọ̀nyí kí ẹ lè mọ̀ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́;+ kò sí ẹlòmíì àfi òun nìkan.+
39 Torí náà, kí o mọ̀ lónìí, kí o sì fi sọ́kàn pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́ lókè ọ̀run àti lórí ilẹ̀ ayé.+ Kò sí ẹlòmíì.+
39 Ẹ rí i báyìí pé èmi, àní èmi ni ẹni náà,+Kò sí ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Mo lè pani, mo sì lè sọni di alààyè.+ Mo lè dá ọgbẹ́+ síni lára, mo sì lè woni sàn,+Kò sí ẹnì kankan tó lè gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ mi.+