1 Sámúẹ́lì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà ń pani, ó sì ń dá ẹ̀mí ẹni sí;*Ó múni sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú Isà Òkú,* ó sì ń gbéni dìde.+ Sáàmù 68:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọlọ́run tòótọ́ ni Ọlọ́run tó ń gbà wá là;+Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sì ń gbani lọ́wọ́ ikú.+