Sáàmù 97:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí ojú ti gbogbo àwọn tó ń sin ère gbígbẹ́,+Àwọn tó ń fi àwọn ọlọ́run asán+ wọn yangàn. Ẹ forí balẹ̀ fún un,* gbogbo ẹ̀yin ọlọ́run.+ Àìsáyà 44:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Gbogbo àwọn tó ń ṣe ère gbígbẹ́ ò já mọ́ nǹkan kan,Àwọn ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí kò ní ṣàǹfààní rárá.+ Bí wọ́n tiẹ̀ jẹ́ ẹlẹ́rìí wọn, wọn* ò rí nǹkan kan, wọn ò sì mọ nǹkan kan,+Torí náà, ojú máa ti àwọn tó ṣe wọ́n.+
7 Kí ojú ti gbogbo àwọn tó ń sin ère gbígbẹ́,+Àwọn tó ń fi àwọn ọlọ́run asán+ wọn yangàn. Ẹ forí balẹ̀ fún un,* gbogbo ẹ̀yin ọlọ́run.+
9 Gbogbo àwọn tó ń ṣe ère gbígbẹ́ ò já mọ́ nǹkan kan,Àwọn ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí kò ní ṣàǹfààní rárá.+ Bí wọ́n tiẹ̀ jẹ́ ẹlẹ́rìí wọn, wọn* ò rí nǹkan kan, wọn ò sì mọ nǹkan kan,+Torí náà, ojú máa ti àwọn tó ṣe wọ́n.+