-
Jeremáyà 5:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nítorí ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà
Ti hùwà àìṣòótọ́ sí mi gan-an,” ni Jèhófà wí.+
-
-
Jeremáyà 9:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ká ní mo ní ibi tí àwọn arìnrìn-àjò lè dé sí ní aginjù!
Mi ò bá fi àwọn èèyàn mi sílẹ̀, kí n sì kúrò lọ́dọ̀ wọn,
Nítorí alágbèrè ni gbogbo wọn,+
Àwùjọ àwọn oníbékebèke.
-