Àìsáyà 48:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Rárá, o ò tíì gbọ́,+ o ò tíì mọ̀ ọ́n,Etí rẹ ò sì là nígbà àtijọ́. Nítorí mo mọ̀ pé ọ̀dàlẹ̀ paraku ni ọ́,+A sì ti pè ọ́ ní ẹlẹ́ṣẹ̀ látìgbà tí wọ́n ti bí ọ.+ Jeremáyà 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 ‘Lóòótọ́, gẹ́gẹ́ bí aya tó hùwà àìṣòótọ́, tó sì kúrò lọ́dọ̀ ọkọ* rẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì ṣe hùwà àìṣòótọ́ sí mi,’+ ni Jèhófà wí.” Hósíà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n ti hùwà àìṣòótọ́ sí Jèhófà,+Torí wọ́n ti bí àwọn ọmọ àjèjì. Ní báyìí, kò ní ju oṣù kan lọ tí àwọn àti ìpín* wọn á fi pa run. Hósíà 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ṣùgbọ́n bí èèyàn lásán-làsàn, wọ́n ti tẹ májẹ̀mú lójú.+ Wọ́n ti hùwà àìṣòótọ́ sí mi ní ilẹ̀ wọn.
8 Rárá, o ò tíì gbọ́,+ o ò tíì mọ̀ ọ́n,Etí rẹ ò sì là nígbà àtijọ́. Nítorí mo mọ̀ pé ọ̀dàlẹ̀ paraku ni ọ́,+A sì ti pè ọ́ ní ẹlẹ́ṣẹ̀ látìgbà tí wọ́n ti bí ọ.+
20 ‘Lóòótọ́, gẹ́gẹ́ bí aya tó hùwà àìṣòótọ́, tó sì kúrò lọ́dọ̀ ọkọ* rẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì ṣe hùwà àìṣòótọ́ sí mi,’+ ni Jèhófà wí.”
7 Wọ́n ti hùwà àìṣòótọ́ sí Jèhófà,+Torí wọ́n ti bí àwọn ọmọ àjèjì. Ní báyìí, kò ní ju oṣù kan lọ tí àwọn àti ìpín* wọn á fi pa run.