ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 48:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Rárá, o ò tíì gbọ́,+ o ò tíì mọ̀ ọ́n,

      Etí rẹ ò sì là nígbà àtijọ́.

      Nítorí mo mọ̀ pé ọ̀dàlẹ̀ paraku ni ọ́,+

      A sì ti pè ọ́ ní ẹlẹ́ṣẹ̀ látìgbà tí wọ́n ti bí ọ.+

  • Hósíà 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ìgbà náà ni Jèhófà sọ fún mi pé: “Lọ lẹ́ẹ̀kan sí i, nífẹ̀ẹ́ ìyàwó rẹ tí ọkùnrin míì ti fẹ́, tó sì ń ṣe àgbèrè,+ bí Jèhófà ṣe nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn Ísírẹ́lì+ bí wọ́n tilẹ̀ lọ sọ́dọ̀ àwọn ọlọ́run míì,+ tí wọ́n sì fẹ́ràn ìṣù àjàrà gbígbẹ.”*

  • Hósíà 5:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Wọ́n ti hùwà àìṣòótọ́ sí Jèhófà,+

      Torí wọ́n ti bí àwọn ọmọ àjèjì.

      Ní báyìí, kò ní ju oṣù kan lọ tí àwọn àti ìpín* wọn á fi pa run.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́