Àìsáyà 51:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹ,Màá sì fi òjìji ọwọ́ mi bò ọ́,+Kí n lè gbé ọ̀run kalẹ̀, kí n sì fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,+Kí n sì sọ fún Síónì pé, ‘Èèyàn mi ni ọ́.’+
16 Màá fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹ,Màá sì fi òjìji ọwọ́ mi bò ọ́,+Kí n lè gbé ọ̀run kalẹ̀, kí n sì fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,+Kí n sì sọ fún Síónì pé, ‘Èèyàn mi ni ọ́.’+