ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 65:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Torí wò ó! Mò ń dá ọ̀run tuntun àti ayé tuntun;+

      Àwọn ohun àtijọ́ ò ní wá sí ìrántí,

      Wọn ò sì ní wá sí ọkàn.+

  • Àìsáyà 66:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ta ló ti gbọ́ irú rẹ̀ rí?

      Ta ló ti rí irú rẹ̀ rí?

      Ṣé a lè bí ilẹ̀ kan ní ọjọ́ kan ni?

      Àbí a lè bí gbogbo orílẹ̀-èdè kan lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo?

      Síbẹ̀, gbàrà tí Síónì bẹ̀rẹ̀ sí í rọbí, ó bí àwọn ọmọkùnrin rẹ̀.

  • Àìsáyà 66:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 “Bí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun+ tí mò ń dá ṣe máa dúró níwájú mi,” ni Jèhófà wí, “bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ* yín àti orúkọ yín ṣe máa dúró.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́