Sáàmù 112:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nínú òkùnkùn, ó ń tàn yanran bí ìmọ́lẹ̀ sí àwọn adúróṣinṣin.+ ח [Hétì] Ó jẹ́ agbatẹnirò* àti aláàánú+ àti olódodo. Àìsáyà 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn èèyàn tó ń rìn nínú òkùnkùn Ti rí ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò. Ní ti àwọn tó ń gbé ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri,Ìmọ́lẹ̀ ti tàn sórí wọn.+ Lúùkù 1:68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 “Ẹ yin Jèhófà,* Ọlọ́run Ísírẹ́lì,+ torí ó ti yíjú sí àwọn èèyàn rẹ̀, ó sì ti gbà wọ́n sílẹ̀.+ Lúùkù 1:79 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 79 láti fún àwọn tó jókòó nínú òkùnkùn àti òjìji ikú ní ìmọ́lẹ̀,+ kó sì darí ẹsẹ̀ wa ní ọ̀nà àlàáfíà.”
4 Nínú òkùnkùn, ó ń tàn yanran bí ìmọ́lẹ̀ sí àwọn adúróṣinṣin.+ ח [Hétì] Ó jẹ́ agbatẹnirò* àti aláàánú+ àti olódodo.
2 Àwọn èèyàn tó ń rìn nínú òkùnkùn Ti rí ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò. Ní ti àwọn tó ń gbé ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri,Ìmọ́lẹ̀ ti tàn sórí wọn.+
79 láti fún àwọn tó jókòó nínú òkùnkùn àti òjìji ikú ní ìmọ́lẹ̀,+ kó sì darí ẹsẹ̀ wa ní ọ̀nà àlàáfíà.”