Àìsáyà 43:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Màá mú ọmọ* rẹ wá láti ìlà oòrùn,Màá sì kó ọ jọ láti ìwọ̀ oòrùn.+ Jeremáyà 31:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 ‘Ìrètí wà fún ọ ní ọjọ́ ọ̀la,’+ ni Jèhófà wí. ‘Àwọn ọmọ rẹ á sì pa dà sí ilẹ̀ wọn.’”+