Ìdárò 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ẹ wo bí Jerúsálẹ́mù tí àwọn èèyàn kún inú rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ṣe wá dá páropáro!+ Ẹ wo bó ṣe dà bí opó, ìlú tó ti jẹ́ eléèyàn púpọ̀ rí láàárín àwọn orílẹ̀-èdè!+ Ẹ wo bí ẹni tó jẹ́ ọbabìnrin láàárín àwọn ìpínlẹ̀* ṣe wá di ẹrú!+
1 Ẹ wo bí Jerúsálẹ́mù tí àwọn èèyàn kún inú rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ṣe wá dá páropáro!+ Ẹ wo bó ṣe dà bí opó, ìlú tó ti jẹ́ eléèyàn púpọ̀ rí láàárín àwọn orílẹ̀-èdè!+ Ẹ wo bí ẹni tó jẹ́ ọbabìnrin láàárín àwọn ìpínlẹ̀* ṣe wá di ẹrú!+