ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 29:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Màá sì jẹ́ kí ẹ rí mi,’+ ni Jèhófà wí. ‘Màá kó yín pa dà láti oko ẹrú, màá sì kó yín jọ láti inú gbogbo orílẹ̀-èdè àti gbogbo ibi tí mo fọ́n yín ká sí,’+ ni Jèhófà wí. ‘Màá sì mú yín pa dà wá sí ibi tí mo ti jẹ́ kí wọ́n kó yín lọ sí ìgbèkùn.’+

  • Jeremáyà 46:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 ‘Ní tìrẹ, má fòyà, ìwọ Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi,

      Má sì jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì.+

      Nítorí màá gbà ọ́ láti ibi tó jìnnà réré

      Àti àwọn ọmọ* rẹ láti oko ẹrú tí wọ́n wà.+

      Jékọ́bù á pa dà, ara rẹ̀ á balẹ̀, kò ní rí ìyọlẹ́nu,

      Ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n.+

  • Hósíà 6:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àmọ́, ìwọ Júdà, a ti dá àkókò ìkórè fún ọ,

      Nígbà tí mo bá kó àwọn èèyàn mi tó wà ní oko ẹrú pa dà.”+

  • Jóẹ́lì 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 “Wò ó! ní àwọn ọjọ́ náà àti ní àkókò yẹn,

      Nígbà tí mo bá dá àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú láti Júdà àti Jerúsálẹ́mù pa dà,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́