Róòmù 8:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ta ló máa fẹ̀sùn kan àwọn àyànfẹ́ Ọlọ́run? + Ọlọ́run ni Ẹni tó pè wọ́n ní olódodo.+