Àìsáyà 50:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹni tó ń pè mí ní olódodo wà nítòsí. Ta ló lè fẹ̀sùn kàn mí?*+ Jẹ́ ká jọ dìde dúró.* Ta ló fẹ́ bá mi ṣe ẹjọ́? Kó sún mọ́ mi.
8 Ẹni tó ń pè mí ní olódodo wà nítòsí. Ta ló lè fẹ̀sùn kàn mí?*+ Jẹ́ ká jọ dìde dúró.* Ta ló fẹ́ bá mi ṣe ẹjọ́? Kó sún mọ́ mi.