Àìsáyà 35:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Aginjù àti ilẹ̀ tí kò lómi máa yọ̀,+Aṣálẹ̀ tó tẹ́jú máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa yọ ìtànná bíi sáfúrónì.+ Àìsáyà 41:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Màá mú kí odò ṣàn lórí àwọn òkè tí nǹkan ò hù sí,+Màá sì mú kí omi sun ní àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀.+ Màá sọ aginjù di adágún omi tí esùsú* kún inú rẹ̀,Màá sì sọ ilẹ̀ tí kò lómi di orísun omi. +
35 Aginjù àti ilẹ̀ tí kò lómi máa yọ̀,+Aṣálẹ̀ tó tẹ́jú máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa yọ ìtànná bíi sáfúrónì.+
18 Màá mú kí odò ṣàn lórí àwọn òkè tí nǹkan ò hù sí,+Màá sì mú kí omi sun ní àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀.+ Màá sọ aginjù di adágún omi tí esùsú* kún inú rẹ̀,Màá sì sọ ilẹ̀ tí kò lómi di orísun omi. +