Ìdárò 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Síónì ti tẹ́ ọwọ́ rẹ̀;+ kò ní ẹni tó máa tù ú nínú. Gbogbo àwọn tó yí Jékọ́bù ká ni Jèhófà ti pàṣẹ fún pé kí wọ́n máa bá a ṣọ̀tá.+ Jerúsálẹ́mù ti di ohun ìríra sí wọn.+
17 Síónì ti tẹ́ ọwọ́ rẹ̀;+ kò ní ẹni tó máa tù ú nínú. Gbogbo àwọn tó yí Jékọ́bù ká ni Jèhófà ti pàṣẹ fún pé kí wọ́n máa bá a ṣọ̀tá.+ Jerúsálẹ́mù ti di ohun ìríra sí wọn.+