Àìsáyà 51:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n máa tó dá ẹni tí wọ́n fi ẹ̀wọ̀n dè, tó sì tẹ̀ ba sílẹ̀;+Kò ní kú, kò sì ní lọ sínú kòtò,Oúnjẹ ò sì ní wọ́n ọn. Àìsáyà 61:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+
14 Wọ́n máa tó dá ẹni tí wọ́n fi ẹ̀wọ̀n dè, tó sì tẹ̀ ba sílẹ̀;+Kò ní kú, kò sì ní lọ sínú kòtò,Oúnjẹ ò sì ní wọ́n ọn.
61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+