-
Àìsáyà 58:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Òdodo rẹ á máa lọ níwájú rẹ,
Ògo Jèhófà á sì máa ṣọ́ ọ láti ẹ̀yìn.+
-
Òdodo rẹ á máa lọ níwájú rẹ,
Ògo Jèhófà á sì máa ṣọ́ ọ láti ẹ̀yìn.+