Ẹ́kísódù 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Áńgẹ́lì Ọlọ́run tòótọ́+ tó ń lọ níwájú àwùjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò níwájú, ó sì bọ́ sí ẹ̀yìn wọn, ọwọ̀n ìkùukùu* tó wà níwájú wọn wá bọ́ sí ẹ̀yìn wọn, ó sì dúró síbẹ̀.+ Àìsáyà 52:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ ò ní fi ìbẹ̀rù lọ,Ẹ ò sì ní sá lọ,Torí Jèhófà máa ṣáájú yín,+Ọlọ́run Ísírẹ́lì á sì máa ṣọ́ yín láti ẹ̀yìn.+
19 Áńgẹ́lì Ọlọ́run tòótọ́+ tó ń lọ níwájú àwùjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò níwájú, ó sì bọ́ sí ẹ̀yìn wọn, ọwọ̀n ìkùukùu* tó wà níwájú wọn wá bọ́ sí ẹ̀yìn wọn, ó sì dúró síbẹ̀.+
12 Ẹ ò ní fi ìbẹ̀rù lọ,Ẹ ò sì ní sá lọ,Torí Jèhófà máa ṣáájú yín,+Ọlọ́run Ísírẹ́lì á sì máa ṣọ́ yín láti ẹ̀yìn.+