-
Róòmù 15:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ní tòótọ́, lọ́nà yìí, mo ní in lọ́kàn pé mi ò ní kéde ìhìn rere níbi tí àwọn èèyàn bá ti mọ orúkọ Kristi, kí n má lọ máa kọ́lé sórí ìpìlẹ̀ ẹlòmíì; 21 gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àwọn tí kò gbọ́ ìròyìn nípa rẹ̀ yóò rí i, àwọn tí kò sì tíì gbọ́ yóò lóye.”+
-