Àìsáyà 52:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Bẹ́ẹ̀ ni òun náà máa dẹ́rù ba ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè.+ Àwọn ọba máa pa ẹnu wọn mọ́* níwájú rẹ̀,+Torí wọ́n máa rí ohun tí wọn ò tíì sọ fún wọn,Wọ́n sì máa ronú nípa ohun tí wọn ò tíì gbọ́.+
15 Bẹ́ẹ̀ ni òun náà máa dẹ́rù ba ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè.+ Àwọn ọba máa pa ẹnu wọn mọ́* níwájú rẹ̀,+Torí wọ́n máa rí ohun tí wọn ò tíì sọ fún wọn,Wọ́n sì máa ronú nípa ohun tí wọn ò tíì gbọ́.+