ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 8:14-17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nígbà tí Jésù wọ ilé Pétérù, ó rí ìyá ìyàwó rẹ̀+ tí àìsàn ibà dá dùbúlẹ̀.+ 15 Ó sì fọwọ́ kan ọwọ́ obìnrin náà,+ ibà náà sì lọ, obìnrin náà wá dìde, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìránṣẹ́ fún un. 16 Àmọ́ nígbà tó di ìrọ̀lẹ́, àwọn èèyàn mú ọ̀pọ̀ àwọn tí ẹ̀mí èṣù ń yọ lẹ́nu wá sọ́dọ̀ rẹ̀; ọ̀rọ̀ ló fi lé àwọn ẹ̀mí náà jáde, ó sì wo gbogbo àwọn tó ń jìyà sàn, 17 kí ohun tí a sọ nípasẹ̀ wòlíì Àìsáyà lè ṣẹ, pé: “Òun fúnra rẹ̀ ru àwọn àìsàn wa, ó sì gbé àwọn àrùn wa.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́