-
Ìṣe 8:32, 33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Àyọkà Ìwé Mímọ́ tó ń kà nìyí: “Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á, bí ọ̀dọ́ àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò la ẹnu rẹ̀.+ 33 Nígbà tí wọ́n ń pẹ̀gàn rẹ̀, wọn ò ṣe ìdájọ́ òdodo fún un.+ Ta ló máa sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ ìran rẹ̀? Nítorí wọ́n gba ẹ̀mí rẹ̀ kúrò ní ayé.”+
-