Jeremáyà 23:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Màá sì gbé àwọn olùṣọ́ àgùntàn dìde lórí wọn tí á máa bójú tó wọn dáadáa.+ Ẹ̀rù ò ní bà wọ́n mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò ní jáyà, kò sì sí ìkankan nínú wọn tó máa sọ nù,” ni Jèhófà wí. Sefanáyà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn tó ṣẹ́ kù lára Ísírẹ́lì+ kò ní hùwà àìṣòdodo;+Wọn kò ní parọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní fi ahọ́n wọn tanni jẹ;Wọ́n á jẹun,* wọ́n á sì dùbúlẹ̀, ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n.”+
4 Màá sì gbé àwọn olùṣọ́ àgùntàn dìde lórí wọn tí á máa bójú tó wọn dáadáa.+ Ẹ̀rù ò ní bà wọ́n mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò ní jáyà, kò sì sí ìkankan nínú wọn tó máa sọ nù,” ni Jèhófà wí.
13 Àwọn tó ṣẹ́ kù lára Ísírẹ́lì+ kò ní hùwà àìṣòdodo;+Wọn kò ní parọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní fi ahọ́n wọn tanni jẹ;Wọ́n á jẹun,* wọ́n á sì dùbúlẹ̀, ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n.”+