ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 38:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ìwọ yóò wá gbéjà ko àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì bí ìgbà tí ìkùukùu* bo ilẹ̀. Ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn, èmi yóò mú kí o wá gbéjà ko ilẹ̀ mi,+ kí àwọn orílẹ̀-èdè lè mọ̀ mí, kí wọ́n sì mọ̀ pé ẹni mímọ́ ni mí nígbà tí wọ́n bá rí ohun tí mo ṣe sí ọ, ìwọ Gọ́ọ̀gù.”’+

  • Ìsíkíẹ́lì 38:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Èmi yóò fi àjàkálẹ̀ àrùn+ àti ikú dá a lẹ́jọ́; èmi yóò mú kí òjò àrọ̀ọ̀rọ̀dá, òkúta yìnyín,+ iná+ àti imí ọjọ́+ rọ̀ lé òun àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ lórí àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀.+

  • Sekaráyà 2:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Torí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, lẹ́yìn tí a ti yìn ín lógo, ó rán mi sí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kó ẹrù yín,+ pé; ‘Ẹni tó bá fọwọ́ kàn yín ń fọwọ́ kan ẹyinjú* mi.+

  • Sekaráyà 12:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ní ọjọ́ yẹn, èmi yóò sọ Jerúsálẹ́mù di òkúta tó wúwo* fún gbogbo èèyàn. Ó dájú pé gbogbo àwọn tó bá gbé e máa fara pa yánnayànna;+ gbogbo orílẹ̀-èdè ayé sì máa kóra jọ láti gbéjà kò ó.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́