Sefanáyà 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Wò ó! Ní àkókò yẹn, màá dojú ìjà kọ gbogbo àwọn tó ń pọ́n ọ lójú;+Màá gba ẹni tó ń tiro là,+Màá sì kó àwọn tó ti fọ́n ká jọ.+ Màá sọ wọ́n di ẹni iyì àti olókìkí* Ní gbogbo ilẹ̀ tí ìtìjú ti bá wọn.
19 Wò ó! Ní àkókò yẹn, màá dojú ìjà kọ gbogbo àwọn tó ń pọ́n ọ lójú;+Màá gba ẹni tó ń tiro là,+Màá sì kó àwọn tó ti fọ́n ká jọ.+ Màá sọ wọ́n di ẹni iyì àti olókìkí* Ní gbogbo ilẹ̀ tí ìtìjú ti bá wọn.