Àìsáyà 41:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Àwọn aláìní àti àwọn tálákà ń wá omi, àmọ́ kò sí rárá. Òùngbẹ ti mú kí ahọ́n wọn gbẹ.+ Èmi Jèhófà máa dá wọn lóhùn.+ Èmi Ọlọ́run Ísírẹ́lì ò ní fi wọ́n sílẹ̀.+
17 “Àwọn aláìní àti àwọn tálákà ń wá omi, àmọ́ kò sí rárá. Òùngbẹ ti mú kí ahọ́n wọn gbẹ.+ Èmi Jèhófà máa dá wọn lóhùn.+ Èmi Ọlọ́run Ísírẹ́lì ò ní fi wọ́n sílẹ̀.+