ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 49:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí:

      “Wò ó! Màá gbé ọwọ́ mi sókè sí àwọn orílẹ̀-èdè,

      Màá sì gbé àmì* mi sókè sí àwọn èèyàn.+

      Wọ́n máa fi ọwọ́ wọn gbé àwọn ọmọkùnrin rẹ wá,*

      Wọ́n sì máa gbé àwọn ọmọbìnrin rẹ sí èjìká wọn.+

  • Àìsáyà 60:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Gbé ojú rẹ sókè, kí o sì wò yí ká!

      Gbogbo wọn ti kóra jọ; wọ́n ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.

      Àwọn ọmọkùnrin rẹ ń bọ̀ láti ọ̀nà jíjìn,+

      Ẹ̀gbẹ́ ni wọ́n sì gbé àwọn ọmọbìnrin rẹ sí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́