Àìsáyà 58:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wọ́n ń wá mi lójoojúmọ́,Inú wọn sì ń dùn láti mọ àwọn ọ̀nà mi,Bíi pé orílẹ̀-èdè olódodo ni wọ́n,Tí kò sì pa ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run wọn tì.+ Wọ́n béèrè ìdájọ́ òdodo lọ́wọ́ mi,Inú wọn ń dùn láti sún mọ́ Ọlọ́run:+
2 Wọ́n ń wá mi lójoojúmọ́,Inú wọn sì ń dùn láti mọ àwọn ọ̀nà mi,Bíi pé orílẹ̀-èdè olódodo ni wọ́n,Tí kò sì pa ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run wọn tì.+ Wọ́n béèrè ìdájọ́ òdodo lọ́wọ́ mi,Inú wọn ń dùn láti sún mọ́ Ọlọ́run:+