Àìsáyà 1:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo* kórìíra àwọn òṣùpá tuntun yín àtàwọn àjọyọ̀ yín. Wọ́n ti di ẹrù ìnira fún mi;Mi ò lè gbé e mọ́. 15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+ Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+
14 Mo* kórìíra àwọn òṣùpá tuntun yín àtàwọn àjọyọ̀ yín. Wọ́n ti di ẹrù ìnira fún mi;Mi ò lè gbé e mọ́. 15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+ Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+