ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 34:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Jèhófà wà nítòsí àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn;+

      Ó ń gba àwọn tí àárẹ̀ bá ẹ̀mí wọn* là.+

  • Sáàmù 147:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó ń mú àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn lára dá;

      Ó ń di àwọn egbò wọn.

  • Àìsáyà 61:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+

      Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+

      Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,

      Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,

      Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+

  • Àìsáyà 66:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 “Ọwọ́ mi ni ó ṣe gbogbo nǹkan yìí,

      Bí gbogbo wọn sì ṣe wà nìyí,” ni Jèhófà wí.+

      “Màá wá wo ẹni yìí,

      Ẹni tó rẹlẹ̀, tí ìbànújẹ́ sì bá ọkàn rẹ̀, tó ń gbọ̀n rìrì* nítorí ọ̀rọ̀ mi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́