Jeremáyà 33:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ‘Wò ó, màá mú kí ara rẹ̀ kọ́fẹ, màá sì fún un ní ìlera,+ màá mú wọn lára dá, màá sì fún wọn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà àti òtítọ́.+ Hósíà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Màá wo àìṣòótọ́ wọn sàn.+ Màá nífẹ̀ẹ́ wọn láti ọkàn mi wá,+Torí pé mi ò bínú sí wọn mọ́.+
6 ‘Wò ó, màá mú kí ara rẹ̀ kọ́fẹ, màá sì fún un ní ìlera,+ màá mú wọn lára dá, màá sì fún wọn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà àti òtítọ́.+