Àìsáyà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọ̀run, sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayé,+Torí Jèhófà ti sọ pé: “Mo ti tọ́ àwọn ọmọ,+ mo sì ti tọ́jú wọn dàgbà, Àmọ́ wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+ Àìsáyà 31:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Ẹ pa dà sọ́dọ̀ Ẹni tí ẹ fi àfojúdi ṣọ̀tẹ̀ sí, ẹ̀yin èèyàn Ísírẹ́lì.+ Àìsáyà 59:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 A ti ṣẹ̀, a sì ti sẹ́ Jèhófà;A ti kẹ̀yìn sí Ọlọ́run wa,A ti sọ̀rọ̀ nípa ìnilára àti ọ̀tẹ̀;+A ti lóyún irọ́, a sì ti sọ̀rọ̀ èké kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ látinú ọkàn.+
2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọ̀run, sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayé,+Torí Jèhófà ti sọ pé: “Mo ti tọ́ àwọn ọmọ,+ mo sì ti tọ́jú wọn dàgbà, Àmọ́ wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+
13 A ti ṣẹ̀, a sì ti sẹ́ Jèhófà;A ti kẹ̀yìn sí Ọlọ́run wa,A ti sọ̀rọ̀ nípa ìnilára àti ọ̀tẹ̀;+A ti lóyún irọ́, a sì ti sọ̀rọ̀ èké kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ látinú ọkàn.+