-
Ìsíkíẹ́lì 18:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 kì í ni ẹnikẹ́ni lára,+ àmọ́ ó máa ń dá ohun tí ẹni tó jẹ ẹ́ ní gbèsè fi ṣe ìdúró pa dà fún un;+ kì í ja ẹnikẹ́ni lólè,+ àmọ́ ó máa ń gbé oúnjẹ rẹ̀ fún ẹni tí ebi ń pa,+ ó sì máa ń da aṣọ bo ẹni tó wà níhòòhò;+ 8 kì í yáni lówó èlé, kì í sì í gba èlé gọbọi lórí owó tó yáni,+ kì í rẹ́ni jẹ;+ ẹjọ́ òdodo ló máa ń dá láàárín ẹni méjì;+
-