Diutarónómì 24:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí ẹni náà bá sì jẹ́ aláìní, ohun tó fi ṣe ìdúró ò gbọ́dọ̀ sun ọ̀dọ̀ rẹ mọ́jú.+ 13 Gbàrà tí oòrùn bá wọ̀ ni kí o rí i pé o dá ohun tó fi ṣe ìdúró pa dà fún un, kó lè rí aṣọ fi sùn,+ á sì súre fún ọ; èyí á sì jẹ́ òdodo lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ.
12 Tí ẹni náà bá sì jẹ́ aláìní, ohun tó fi ṣe ìdúró ò gbọ́dọ̀ sun ọ̀dọ̀ rẹ mọ́jú.+ 13 Gbàrà tí oòrùn bá wọ̀ ni kí o rí i pé o dá ohun tó fi ṣe ìdúró pa dà fún un, kó lè rí aṣọ fi sùn,+ á sì súre fún ọ; èyí á sì jẹ́ òdodo lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ.