Jeremáyà 14:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwà wa jẹ́rìí sí i pé a ti ṣe àṣìṣe,Jèhófà, ràn wá lọ́wọ́ nítorí orúkọ rẹ.+ Nítorí ìwà àìṣòótọ́ wa pọ̀,+Ìwọ sì ni a dẹ́ṣẹ̀ sí. Hósíà 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìwà Ísírẹ́lì ti jẹ́rìí sí i* pé ó gbéra ga;+Àṣìṣe Ísírẹ́lì àti Éfúrémù ti mú kí wọ́n kọsẹ̀,Júdà sì ti kọsẹ̀ pẹ̀lú wọn.+
7 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwà wa jẹ́rìí sí i pé a ti ṣe àṣìṣe,Jèhófà, ràn wá lọ́wọ́ nítorí orúkọ rẹ.+ Nítorí ìwà àìṣòótọ́ wa pọ̀,+Ìwọ sì ni a dẹ́ṣẹ̀ sí.
5 Ìwà Ísírẹ́lì ti jẹ́rìí sí i* pé ó gbéra ga;+Àṣìṣe Ísírẹ́lì àti Éfúrémù ti mú kí wọ́n kọsẹ̀,Júdà sì ti kọsẹ̀ pẹ̀lú wọn.+