ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 17:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àwọn èèyàn Júdà pàápàá kò pa àwọn àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run wọn mọ́;+ àwọn náà ń tẹ̀ lé àṣà tí Ísírẹ́lì tẹ̀ lé.+ 20 Jèhófà kọ gbogbo àtọmọdọ́mọ Ísírẹ́lì sílẹ̀, ó dójú tì wọ́n, ó sì fi wọ́n lé ọwọ́ àwọn tó ń kóni lẹ́rù, títí ó fi lé wọn kúrò níwájú rẹ̀.

  • Ìsíkíẹ́lì 23:30, 31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Wọ́n á ṣe gbogbo nǹkan yìí sí ọ torí ò ń sáré tẹ̀ lé àwọn orílẹ̀-èdè bí aṣẹ́wó,+ torí o fi àwọn òrìṣà ẹ̀gbin wọn sọ ara rẹ di ẹlẹ́gbin.+ 31 Ohun tí ẹ̀gbọ́n rẹ ṣe ni ìwọ náà ń ṣe,+ màá sì fi ife rẹ̀ lé ọ lọ́wọ́.’+

  • Émọ́sì 2:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

      ‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Júdà+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,

      Nítorí pé wọn kò tẹ̀ lé òfin* Jèhófà

      Àti nítorí pé wọn kò pa àwọn ìlànà rẹ̀ mọ́;+

      Irọ́ tí àwọn baba ńlá wọn tọ̀ lẹ́yìn ti mú kí wọ́n ṣìnà.+

       5 Torí náà, màá rán iná sí Júdà,

      Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ní Jerúsálẹ́mù run.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́