Jeremáyà 9:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n ya alágídí, wọ́n ń ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ,+ wọ́n sì ń tẹ̀ lé àwọn ère Báálì bí àwọn bàbá wọn ṣe kọ́ wọn.+
14 Kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n ya alágídí, wọ́n ń ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ,+ wọ́n sì ń tẹ̀ lé àwọn ère Báálì bí àwọn bàbá wọn ṣe kọ́ wọn.+