Àwọn Onídàájọ́ 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, wọ́n gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń sin àwọn Báálì+ àti àwọn òpó òrìṣà.*+ 1 Sámúẹ́lì 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́,+ wọ́n sọ pé, ‘A ti dẹ́ṣẹ̀,+ nítorí a ti fi Jèhófà sílẹ̀ lọ sin àwọn Báálì+ àti àwọn ère Áṣítórétì;+ ní báyìí gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, kí a lè sìn ọ́.’ Hósíà 11:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí wọ́n* ti ń pe àwọn èèyàn Ísírẹ́lì,Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń sá fún wọn.+ Àwọn ère Báálì ni wọ́n ń rúbọ sí+Wọ́n sì ń rúbọ sí àwọn ère gbígbẹ́.+
7 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, wọ́n gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń sin àwọn Báálì+ àti àwọn òpó òrìṣà.*+
10 Wọ́n ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́,+ wọ́n sọ pé, ‘A ti dẹ́ṣẹ̀,+ nítorí a ti fi Jèhófà sílẹ̀ lọ sin àwọn Báálì+ àti àwọn ère Áṣítórétì;+ ní báyìí gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, kí a lè sìn ọ́.’
2 Bí wọ́n* ti ń pe àwọn èèyàn Ísírẹ́lì,Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń sá fún wọn.+ Àwọn ère Báálì ni wọ́n ń rúbọ sí+Wọ́n sì ń rúbọ sí àwọn ère gbígbẹ́.+