Sáàmù 149:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí inú Jèhófà ń dùn sí àwọn èèyàn rẹ̀.+ Ó ń fi ìgbàlà ṣe àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ lọ́ṣọ̀ọ́.+ Àìsáyà 52:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+ Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́! Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+ Àìsáyà 55:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wò ó! O máa pe orílẹ̀-èdè tí o kò mọ̀,Àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè tí kò mọ̀ ọ́ sì máa sáré wá sọ́dọ̀ rẹ,Torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Torí pé ó máa ṣe ọ́ lógo.+
52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+ Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́! Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+
5 Wò ó! O máa pe orílẹ̀-èdè tí o kò mọ̀,Àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè tí kò mọ̀ ọ́ sì máa sáré wá sọ́dọ̀ rẹ,Torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Torí pé ó máa ṣe ọ́ lógo.+