Ìfihàn 21:25, 26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 A ò ní ti ẹnubodè rẹ̀ rárá ní ọ̀sán, torí pé ilẹ̀ ò ní ṣú níbẹ̀.+ 26 Wọ́n sì máa mú ògo àti ọlá àwọn orílẹ̀-èdè wá sínú rẹ̀.+
25 A ò ní ti ẹnubodè rẹ̀ rárá ní ọ̀sán, torí pé ilẹ̀ ò ní ṣú níbẹ̀.+ 26 Wọ́n sì máa mú ògo àti ọlá àwọn orílẹ̀-èdè wá sínú rẹ̀.+