Àìsáyà 60:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ẹnubodè rẹ máa wà ní ṣíṣí nígbà gbogbo;+Wọn ò ní tì wọ́n ní ọ̀sán tàbí ní òru,Láti mú ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè wá sọ́dọ̀ rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣáájú.+ Àìsáyà 60:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Oòrùn rẹ ò ní wọ̀ mọ́,Òṣùpá rẹ ò sì ní wọ̀ọ̀kùn,Torí pé Jèhófà máa di ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,+Àwọn ọjọ́ ọ̀fọ̀ rẹ sì máa dópin.+
11 Àwọn ẹnubodè rẹ máa wà ní ṣíṣí nígbà gbogbo;+Wọn ò ní tì wọ́n ní ọ̀sán tàbí ní òru,Láti mú ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè wá sọ́dọ̀ rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣáájú.+
20 Oòrùn rẹ ò ní wọ̀ mọ́,Òṣùpá rẹ ò sì ní wọ̀ọ̀kùn,Torí pé Jèhófà máa di ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,+Àwọn ọjọ́ ọ̀fọ̀ rẹ sì máa dópin.+