Sekaráyà 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kún fún ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì. Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù. Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.+ Olódodo ni, ó sì ń mú ìgbàlà bọ̀,*Ó jẹ́ onírẹ̀lẹ̀,+ ó sì ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,Àní ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,* ọmọ abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+ Mátíù 21:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé: ‘Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ,+ oníwà tútù ni,+ ó sì gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àní, ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ọmọ ẹran akẹ́rù.’”+ Jòhánù 12:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Má bẹ̀rù, ọmọbìnrin Síónì. Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀, ó jókòó sórí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.”*+
9 Kún fún ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì. Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù. Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.+ Olódodo ni, ó sì ń mú ìgbàlà bọ̀,*Ó jẹ́ onírẹ̀lẹ̀,+ ó sì ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,Àní ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,* ọmọ abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+
5 “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé: ‘Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ,+ oníwà tútù ni,+ ó sì gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àní, ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ọmọ ẹran akẹ́rù.’”+